HYMN 393

O.t.H.C 136 C.M (FE 416)
"Oruko re ni Iyanu" - Isa 9:61. OLORUN Olodumare 

   Baba, Omo, Emi 

   Riri enit'a ko le mo 

   Eniti‘a ko Ie ri.


2. Ye! Baba Olodumare 

   K‘a wariri fun O

   Ni gbogbo orile ede 

   Li a o ma sin O.


3. Olorun omo, Ore wa 

   Wo t'o ra wa pada 

   Ma jowo wa, Olugbala! 

   Gba wa patapata.


4. A! Olorun Emi Mimo 

   ‘Wo olore‐ofe

   A be O, fun wa ni imo 

   K'a m'Olorun n'ife.


5. Okansoso sugbon meta 

   Eni Metalokan

   Olorun awamaridi 

   Eni Metalokan. Amin

English »

Update Hymn