HYMN 394

t.H 577 6s 8s (FE 417)
"Nwon si fi ogo, ati ola, ati ope, fun 
eniti o joko lori ite" - Ifi 4:91. MO f’iyin ailopin

   Fun Olorun baba 

   Fun ore aiye mi 

   At'ireti t’orun

   O ran Omo Re ayanfe 

   Lati ku fun ese aiye.


2. Mo f'iyin ailopin 

   Fun Olorun Omo 

   T'O f‘eje Re we wa 

   Kuro ninu egbe 

   Nisisiyi O wa l'Oba 

   O nri eso irora Re.


3. Mo f‘iyin ailopin 

   Fun Olorun Emi 

   Eni f ’agbara Re 

   So elese d’aye

   O pari ise igbala 

   O si fi ayo kun okan.


4. Mo f’ola ailopin

   Fun Olodumare

   Wo Ologo meta

   Sugbon okansoso 

   B’O ti ju imo wa lo ni,

   A o ma f’igbagbo yin O. Amin

English »

Update Hymn