HYMN 396

H.C 487 7S (FE 419)
"Emi ti fe ofin re to" - Ps. 119:97
1. BIBELI mimo t’orun 

   Owon isura t‘emi

   Wo ti nwi bi mo ti ri 

   Wo ti nso bi mo ti wa.


2. Wo nko mi, bi mo sina

   Wo nf'ife Oluwa han 

   Wo ti nwi bi mo ti ri

   Wo ti nso bi mo ti wa.


3. ‘Wo n’ima tu wa ninu

   Ninu wahala aiye

   Wo nko ni, nipa gbagbo

   Pe, a le segun iku.


4. Wo l’o nso t’ayo ti mbo 

   At’ iparun elese 

   Bibeli mimo t’orun 

   OwoN isura t’emi. Amin

English »

Update Hymn