HYMN 397

(FE 420) 119 2nd Pt t.H.C 400 C.M
"Nipa ewo Ii odomokunrin yio fi mu 
ona Re mo? Nipa ikiyesi gegebi oro re"
 - Ps. 119:91. BAWO ni awon ewe wa 

   Y‘o ti ma sora won?

   Bikose ‘nipa kiyesi 

   Gegebi oro Re.


2. Gba oro na wo ‘nu okan 

   A tan imole ka

   Oro na ko ope l‘ogbon 

   At‘imo Olorun.


3. Orun ni, imole wa ni 

   Amona wa l'osan 

   Fitila ti nfonahan wa 

   Ninu ewu oru.


4. Oro Re, oto ni titi 

   Mimo ni gbogbo re 

   Amona wa l’ojo ewe 

   Opa l’ojo ogbo. Amin

English »

Update Hymn