HYMN 404

H.C 133 C.M. (FE 427)
“Oluwa ise Re ti pio to!" - Ps. 104:241. IWE kan wa ti kika re

   Ko soro fun enia

   Ogbon ti awon t’o ka nfe 

   Ni okan ti o mo.


2. lse gbogbo t’Olorun se 

   L'oke n’ile, n'nu wa 

   Nwon j’okan ninu iwe na 

   Lati f’Olorun han.


3. Imole osupa l’oke 

   Lat’ odo orun ni 

   Be l’ogo Ijo Olorun 

   T’odo Olorun wa.


4. lwo ti O jeki a ri 

   Ohun t‘o dara yi

   Fun wa l‘okan lati wa O

   K'a ri O nibi gbogbo. Amin

English »

Update Hymn