HYMN 405

O.t.H. 229 C.M. (FE 428) 
"Mo ri oro Re mo si je won " - Jer. 15:161. BIBELI iwe aiyeraiye

   Tani le r’idi re? 

   Tani Ie so idide re? 

   Tani le m'opin re?


2. Asiri Olodumare 

   Iko Oba orun 

   Ida t’o pa oro iku 

   Aworan Olorun.


3. Okan ni O larin opo 

   Iwe aiye ‘gbani

   lwo l‘o s’ona igbala 

   Di mimo f’araiye.


4. Isura ti Metalokan 

   Oba nla t’o gunwa

   Jo, tumo ara Re fun mi 

   Ki m'ye siyemeji.


5. Ki m’si o p pelu adura

   Ki ‘m’k‘ eko ninu re 

   Iwo lwe Aiyeraiye, 

   F’ife Jesu han mi. Amin

English »

Update Hymn