HYMN 410

(FE432)
C.M.S 301, H.C 276. C.M
"Olorun aiyeraiye ki isare, ko si a 
awari oye Re" - Isa 40:281. OJU kan mbe ti ki togbe

   Nigbat’ile ba su

   Eti kan mbe ti ki ise

   ‘Gbat orun ba wo.


2. Apa kan mbe ti ko le re 

   Gba ‘pa enia pin

   Ife kan mbe ti ko le ku 

   Gba fe aiye ba ku.


3. Oju na nwo awon Serafu 

   Apa na d’orun mu

   Eti na kun f’orin Angel

   lfe na ga loke.


4. lpa kan l’enia le lo 

   Gbat ipa gbogbo pin 

   Lati ri oju at’apa

   Ati ife nla na.


5. lpa na ni adura wa

   Ti nlo ‘waju ite

   To nmi owo t’o s’aiye ro 

   Lati mu ‘gbala wa.


6. Iwo t’anu re ko lopin 

   T’ife Re ko le ku

   Je k’a n’igbagbo at’ife 

   K’a le ma gbadura. Amin

English »

Update Hymn