HYMN 416

(FE 439) C.M.S 531 C.H. t.H.C 145 7s 
"‘Enyin o si saferi mi, e o si ri mi, 
ti e ba fi gbogbo okan nyin wa mi”
 - Jer. 29:131. OLUWA, awa’do Re 

   L’ese Re l’a kunle si 

   A! ma kegan ebe wa

   Ao wa lasan bi!


2. L’ ona to O yan fun wa 

   L’a nwa O lowolowo 

   Oluwa a ki o lo

   Titi ‘Wo o bukun wa.


3. Ranse lat’oro Re wa 

   Ti O fi ayo‐fun wa 

   Je ki emi Re ko fun 

   Okan wa ni igbala.


4. Jek’a wa, k’a si ri O

   Ni Olorun Olore

   W’alasian, da ‘gbekun si,

   Ki gbogbo wa yo si O. Amin

English »

Update Hymn