HYMN 419

(FE 442)
C.M.S 540 t.H.C 289. C.M.
"Omo mi fi okan re fun mi” 
- Owe 23:261. GB'OKAN mi gegeb’ o ti ri 

   Te ite Re sibe

   Ki nle fe O ju aiye lo 

   Ki nwa fun O nikan.


2. Pari ‘se Re Oluwa mi

   Mu mi je oloto

   K'emi le gbohun Re, Jesu 

   Ti o kun fun ife.


3. Ohun ti nko mi n’ife Re 

   Ti nso ‘hun ti mba se

   Ti ndoju ti mi, nigba nko 

   Ba topa ona Re.


4. Emi ‘ba ma ni eko yi

   To ati Odo Re wa,

   Ki nko ‘teriba s'ohun Re 

   At‘oro isoye. Amin

English »

Update Hymn