HYMN 421

C.M.S 539 t.H.C 154 C.M (FE 444) 
“Mase je ki awon ti nwa O ki o damu” 
- Ps. 69:61. WO bi awa enia Re

   Ti wole l'ese Re 

   Olorun ! kiki anu Re 

   Ni igbekele wa.


2. ldajo t'o ba ni leru 

   Nfi agbara Re han 

   Sibe anu da ‘lu wa si 

   Awa si ngbadura.


3. Olorun, o se da wa si 

   Awa alaimore?

  Jo, je k‘agbo ikilo Re 

  Nigbati anu wa.


4. lwa buburu ti po to 

   Yika ile wa yi! 

   Buburu ile wa lo to ‘yi 

   Wo b’o ti buru to.


5. Oluwa, fi ore-ofe

   Yi wa lokan pada!

   Ki a le gba oro Re gbo 

   K’a si wa oju Re. Amin

English »

Update Hymn