HYMN 424

C.S.M 537 T.C.H 51 L.M (FE 447) 
"Omo Olorun ye, o si li agbara" - Heb.4:121. JE ki ilekun aitase

   Si fun ise wa, Oluwa 

   Ti o si ti ki o ti mo 

   Ilekun ‘wole oro re.


2. F‘owo ina to ete won

   Ti nfi’ lana Re han aiye

   F'ife mimo si aiya won

   Ti Olorun at'enia.


3. F'itara fun iranse Re,

   T’ohun kan ko le mu tutu

   Bi nwon si ti ntan oro Re

   Bukun imo at’ise won.


4. Ran Emi Re lat'oke wa

   Ma je ki agbara Re pin

   Tit'irira o fi pari,

   Ti gbogbo ija o si tan. Amin

English »

Update Hymn