HYMN 437

C.M.S 316 C.M (FE 461)
“Isun kartyia si rilefunare allfun
iwa aimo" - Sek. 13:11. ISUN kan wa to kun f'eje 

   O yo nihan jesu 

   Elese mokun ninu re

   O bo ninu ebi.


2. ‘Gba mo f'igbagbo r’isun na 

   Ti nsan fun ogbe Re

   Irapada d’orin fun mi

   Ti ngo ma ko titi.


3. Ninu orin to dun julo 

   L’emi o korin Re 

   Gbat‘akololo ahon yi 

   Ba dake n’iboji.


4. Mo gbagbo p‘O pese fun mi 

   Bi mo tile saiye

   Ebun ofe ta f’eje ra 

   Ati duru wura.


5. Duru t'a tow’Olorun se, 

   Ti ko ni baje lai

   T'a o ma fi iyin Baba wa 

   Oruko Re nikan. Amin

English »

Update Hymn