HYMN 449

K.III. t.H.C (FE 474) S.M 
“Ma beru, emi wa pelu re” 
- Gen. 26:241. F’ERU re f’afefe

   N’ireti ma foiya 

   Olorun gbo ‘mikanle re

   Yio gb’ori re ga.


2. N’irumi at’iji

   Y’o s’ona re fefe 

   Duro de igba Re, oru 

   Y’o pin s’ojo ayo.


3. Iwo r’ailera wa

   Inu wa n’iwo mo 

   Gbe owo t’o re si oke 

   M’ekun ailera le.


4. K’awa, n'iyen n’iku 

   So, oro Re tantan

   K’a so tit’ opin emi wa 

   Ife, itoju Re. Amin

English »

Update Hymn