HYMN 453

t.H.C 271 (2nd Tune) 
8.8.8.8.4 (FE 478) Ps. 43:5
Tune: lja Dopin1. JESU, Olugbala, wo mi 

   Are mu mi, ara nni mi 

   Mo de lati gb'ara le O 

   Wo ‘simi mi.


2. Bojuwo mi o re mi tan 

   Irin ajo na gun fun mi

   Mo nwa ‘ranwo agbara Re 

   Wo Ipa mi.


3. Idamu ba mi lona mi 

   Oru sokun, iji si nfe 

   Tan imole si ona mi 

   ‘Wo Mole mi.


4. Gba Satani ba tafa re

   Wo ni mo nwo, nko beru mo 

  Agbelebu Re l’abo mi, 

  Wo Alafia mi.


5. Mo nikan wa leti Jordan

   Ninu ‘waiya‐ja jelo ni

   Wo ki yio je k’emi ri

   Wo lye mi. 


6. Gbogbo aini, ‘Wo o fun mi 

   Titi d’opin l'onakona

   Ni ‘ye, ni 'ku titi Iailai 

   Wo gbogbo mi. Amin

English »

Update Hymn