HYMN 459

C.H. t.H.C 150 C.M (FE 484)
“Ma da mi ro" - Gen. 24:56
1. L'ONA gbogbo t'Oluwa yan

   Ajo mi l' em‘ o to

  Ma da mi ro, enyin mimo 

  Emi o ba nyin lo.


2. Bi Jesu nlo ninu ina

   Emi o to lehin 

   Ma da mi ro, l'emi o ke

   Bi aiye d'ojuko mi


3. Ninu isin at'idanwo

   Em'o lo l'ase Re
 
   Ma da mi ro, emi o lo

   S'ile Emmanuel.

 
4. 'Gba Olugbala mi ba pe

   Sibe, K'igbe mi je 

   Ma da mi ro, iku ma bo

   Ngo ba o lo l'ayo. Amin
4. 

English »

Update Hymn