HYMN 495

C.M.S 506 H.C 2nd Ed
457 t.H.C 528 L.M (FE 521)
“Emi fi ohun mi kigbe si Olorun
O si fe eti si mi“ - Ps.77:11. OLORUN mi, ‘Wo l‘emi o pe

   Ara nni mi, gbo igbe mi

  Gba'san omi ba bori mi 

  Ma je k’okan mi fa sehin.


2. lwo Ore alailera

   Tani mba s’aroye mi fun 

   Bikose ‘Wo nikansoso 

   T'o npe otosi wodo Re?


3. Tal'o sokun to O lasan ri? 

   Wo koi gbagbe enikan ri 

   Se lwo ni O ti so pe 

   Enikan k' yo wa O lasan?


4. Eyi ’ba je ‘banuje mi

   Pa, O ko ndahun adura 

   Sugbon ‘Wo ti ngbo adura 

   lwo l‘O nse iranwo mi.


5. Mo mo pe alaini l’emi

   Olorun Ko ni gbagbe mi

   Eniti Jesu mbebe fun

   O bo Iowo gbogbo ‘yonu. Amin
 

English »

Update Hymn