HYMN 496

C.M.S 584 t.H.C 318 C.M (FE 522)
"Eniti o si tan gbogbo re" - Ps.103:31. ENIT‘O la ju afoju 

   Ti O mu ope gbon 

   At’enit'O da imole 

   Fun eni okunkun.


2. Enit'O le fi agbara 

   F’awon olokunrun 

   Ti O si fi emi iye 

   Fun awon t'o ti ku.


3. Eni fi ‘dasile f'okan 

   T'O gb’eni subu nde

   T’O si pa ibanuje da 

   S’orin pelu iyin.


4. Wo Onisegun okan mi 

   Si O l’awa nkorin

   Titi aiye o fi d’opin 

   Tire l’ope o se. Amin 

English »

Update Hymn