HYMN 50

(FE67)
Tune:  Alejo kan nkan ‘lekun G.B
190  “Baba gbo, Baba dariji”1.  BABA Oludariji, Dariji 

Gbogbo awa omo Re, Dariji,

Awa Egbe Serafu,

Ati Egbe Kerubu 

Ati npafo ninu ese, Dariji.


2.  JESU OLUGBALA WA Dariji

OLURADAPA Eda Dariji,

Wo to mbebe f‘ota Re 

L'origi Agbelebu 

Wipe fiji won BABA Dariji.


3.  EMI OLUTUNU wa, Daniji

Gbogbo ebi ese wa, Dariji 

Gba wa lojo idamu 

Se Oluranlowo wa,

Mase jeki a bohun Dariji.


4.  METALOKAN jowo wa Dariji

Omode ati Agba Dariji,

JAH JEHOVAH RAMMAH 

‘Wo l’Oba Oniyonu,

Dariji ‘se owo Re Dariji.  Amin

English »

Update Hymn