HYMN 506

H.C 123, 579 10s 11s (FE 534)
"Nwon ko si simi losan ati laju, wipe,
Mino, Mimo, Mimo" - Ifihan.4:8
Tune: Aigbagbo bila temi l’Oluwa
1. KERUBU e yo, Serafu e yo 

   F‘egbe Mimo yi ti Baba fun wa

   T'o ju ogbon ati ero eda lo 

   Ogo, lyin, Ola fun Metalokan.


2. Eda ko nipa lori Egbe yi 

   Sa ma se rere iwo yio segun

   Ma si se fi Eda se ‘gbekele Re 

   OIorun Eleda ko ni gbagbe Re.


3. Aje ko n’ipa lori Egbe yi 

   Oso ko n‘ipa lori Egbe yi

   Sa te le ona t’Oluwa la sile 

   lsegun y‘o je tire lona gbogbo.


4. Kerubu nkigbe, Eda ko mira 

   Serafu nkigbe, Eda ko bere

   Awawi ko ni si fun nyin lojo na 

   T’eda t'Angeli yio pelu dandan.


5. Olodumare gbo adura mi 

   Ki nle tele O d’opin aiye mi

   Ki oju ma ti mi ni opin aiye mi 

   Ki ngbo, o se omo, bo si aye re.


6. Ghana la o ko ‘rin Halleluya 

   Ni’waju ite Olodumare 

   T‘Olugbala y’o tan mole Re si wa 

   K‘ori awa mase ko ‘ye ainipekun.


7. Ogo fun Baba, Ogo fun Omo 

   Ogo f’Emi Mimo, Metalokan 

   B’ero eda ko tile mo ‘jinle Re 

   A o ma yin O sibe titi aiye. Amin

English »

Update Hymn