HYMN 536

t.H.C 18 C.M. (FE 562)
"Kiyesi o ti dara o si ti dun“ - Ps.113:11. WO! b’o ti dun to lati ri 

   Awon ara at'ore

   Ara ti okan won s’okan 

   L’egbe ide mimo.


2. Gba isan ‘fe t'odo Krist sun

   O san s'okan gbogbo 	

   Alafia Olodumare

   Dabobo gbogbo re.


3. O dabi ororo didun

   Ni irugbon Aaron

   Kikan re m'aso re run ‘re 

   O san s’agbada re.


4. O dara b‘iri owuro

   To nse soke Sion

   Nibit Olorun f‘ogo han 

   T'o m’ore-ofe han. Amin

English »

Update Hymn