HYMN 537

C.M.S 349 H.C 11s (FE 563) 
“So mi di aye" - Ps. 119:251. Fun mi n’iwa mimo 

   Igbona okan

   Suru ninu iya, aro fun ese 

   Igbagbo n’nu Jesu:

   ki nmo ‘toju Re;

   Ayo n’nu isin Re;

  emi adura.


2. Fun mi l’okan ope,

   igbkele Krist’

   Itara f’ogo Re ‘reti n’nu Oro Re 

   Ekun fun iya Re; ‘rora f’ogbe Re 

   Irele n’nu ‘danwo;

   iyin fun ‘ranwo.


3. Fun mi n’iwa funfun 

   fun ni n'isegun

   We abawon mi nu'fa 

   ‘fe mi s’orun

   Mu mi ye ‘joba Re, ki nwulo fun O 

   Ki nj’alabukun fun, ki ndabi Jesu. Amin

English »

Update Hymn