HYMN 552

C.M.S 572 H.C 589 L.M (FE 579)
“Olorun igbala wa, eniti ise igbekele 
gbgogbo opin ile aiye, ati okun ti o 
jina rere" - Ps.65:51. BABA, jowo gb’adura wa 

   Bi a ti nlo loju omi

   Iwo maje ebute wa 

   At’ile wa loju omi.


2. Jesu Olugbala ‘Wo ti 

   O ti mu ‘ji dake roro 

   Ma je ayo fun asofo 

   Fi simi ‘fokan aibale.


3. Wo Emi Mimo, Eniti 

   O rababa loju omi 

   Pase ‘bukun lakoko yi 

   Fi ipa Re mu wa soji.


4. Wo Olorun Metalokan

   Ti awa nsin, ti awa mbo 

   Ma se’bi sadi wa l’aiye 

   Ati ayo wa li orun. Amin

English »

Update Hymn