HYMN 59

S.S. & S.16 (FE 76)
“Emi si wipe, Iwo o pe mi ni Baba mi"
- Jer. 3:191. IRAPADA; ltan iyanu,

   Ni ayo fun o at'emi,

   Pe Jesu ti ra idariji

   O san gbese na lori ‘gi.

Egbe: A! ‘wo elese gba eyi gbo

      Gba ihin otito no gbo

      Gbeke l 'eni to ku Iori 'gi

      To mu igbala wa fun o.


2. Gbani Olorun nisisiyi

   Segun agbar'ese fun wa,

   'Tori on yio gba enito wa

   Ki yio si ta o nu lailai.

Egbe: A! ‘wo elese gba...


3. Ese ki yio fun lagbara mo,

   Bi ko tile ye dan wa wo,

   Nipa ise ‘rapada Kristi

   Agbara ese yio parun.

Egbe: A! ‘wo elese gba...


4. O mu wa lat' iku bo si iye

   O si so wa d’om’Olorun

   Orisun kan si fun elese

   We nin’ eje na ko si mo.

Egbe: A! ‘wo elese gba...


5. Gba anu t'Olorun fi lo o

   Sa wa sodo Jesu loni

   ‘Tori y'o gb'eni to ba to wa

   Ki yio si pada lailai.

Egbe: A! ‘wo elese gba... Amin 

English »

Update Hymn