HYMN 606

11s (FE 632)
"Emi o kigbe pe O, Oluwa, ati si 
Oluwa li emi mbebe gidigidi"
 - Ps. 30:81. GBE ‘banuje re mi 

   o ka ri aiye

   Fi s‘ohun igbagbo 

   roju pa mora

   Fi suru ronu re/li oru ‘ganjo

   To Jesu lo ro fun/yio si san fun o.


2. To Jesu lo, ro fun, O mo edun re, 

   To Jesu lo, ro fun, yio ran o lowo 

   Lo je k’adun ayo/to pese fun O 

   Yio m’eru re fuye/sa lo gbadura.


3. Awon ti osi won/po ju tire lo

   N’sori ko n‘nu okun, lo tun won ninu 

   Gbe ‘banuje re mi, f’elomi layo

   Lo tan ‘mole fun won

   f’abo fun Jesu. Amin

English »

Update Hymn