HYMN 607

C.M.S 409 S. 71. 6. 4. 6. s.(FE 633)
“Loni bi eniyin ba fe gbohun Re, 
e ma se aiya nyin le" - Ps. 95:7, 81. LONI ni Jesu pe! 

   Asako wa

   A! okan okunkun 

   Ma kiri mo.


2. Loni Jesu pe? 

   Tetilele

   Wole fun Jesu, ni 

   Le owo yi.


3. Loni ni Jesu pe! 

   Sa asala

   Iji igbesan mbo 

   Iparun mbo.


4. Loni ni Emi pe! 

   Jowo ‘ra re 

   Ma mu k’o binu lo 

   Sa anu ni. Amin

English »

Update Hymn