HYMN 618

C.M.S 446, t.H.C. 149. C.M (FE 644)
“Bikosepe a tun enia bi nipa omi ati 
nipa Emi, On ki yio le wo Ijoba 
Orun" - John 3:5


1. EY l'ase nla Jehovah 

   Yio wa titi lai

   Elese b’lwo at’emi

   K‘a tun gbogbo wa bi.


2. Okunkun y‘o je ipa wa 

   B’a wa ninu ese

   A ki o ri ijoba Re

   Bi a ko d'atunbi.


3. Bi baptisi wa je’gbarun 

   Asan ni gbogbo re

   Eyi ko lew’ese wa nu

   Bi a ko tun wa bi.


4. Wo ise were ti a nse

   Koni iranwo re

   Nwon ko s‘okan wa di otun

   B’awa ko d‘atunbi.


5. Lo kuro ninu ese re

   Ja ewon Esu nu

   Gba Kristi gbo tokantokan

   lwo o d’atunbi. Amin

English »

Update Hymn