HYMN 633

H.C. 520 C.M (FE 659)
"Tire l'emi gbamilla" - Ps 119:941. TIRE titi lai l'awa se

   Oluwa wa orun

   K'ohun at'okan wa wipe

   Amin, beni k'o ri.


2. Gbati aiye ba ndun mo ni 

   T'o si nfa okan wa

   K'iro yi pe, 'Tire l’awa 

   Lema dun l'eti wa.


3. Gbat' ese pelu etan re 

   Ba fe se wa n’ibi

   K'iro yi pe, 'Tire l’awa

   Tu etan ese ka.


4. Gbati Esu ba ntafa re 

   S’ori ailera wa

   K’iro yi pe, ‘Tire l’awa 

   Ma je ki o re wa.


5. Tire n'igb’awa l’Omode 

   Tire n'igba a ndagba 

   Tire n'igb'a ba darugbo 

   Ti aiye wa mbuse.


6. Tire titi lai l‘awa se

   A f' ara wa fun O

   Tlti aiye ainipekun 

   Amin, beni k'o ri. Amin

English »

Update Hymn