HYMN 65

(FE 33)
"Wa si orisun na" - Ps. 36:91. ELESE wa s'orisun na,

   Wa pelu 'banuje re,

   Ri won sinu omi jijin

   'Wo y‘o r'irorun nibe

Egbe: Yara kalo, mase duro

      lseju kan le so emi re nu

      Jesu nduro Iati gba o,

      Anu mbe fun o loni.


2. Wa t’iwo t’eru ese re

   Jesu ti nduro de o,

   B’ese re pon bi alari,

   Nwon yio funfun bi sno.

Egbe: Yara kalo, mase duro...


3. Jesu olugbala wipe,

   Awon ti o ba gbagbo

  Ti nwon si ronupiwada

  Y’o r’iye gba lodo re.

Egbe: Yara kalo, mase duro...


4. Wa we ninu orisun na,

   F‘eti si ohun ife

   Jeki awon Angeli yio

   F’elese to yi pada.

Egbe: Yara kalo, mase duro... Amin

English »

Update Hymn