HYMN 651

C.M.S 436 H.C 2nd Ed 382,
t.H.C 225 C.M (FE 677)
"Emi ki yio mu ninu eso ajara mo titi 
de ojo na, nigbati emi o si ba nyin mu 
u ni titu ni ljoba Baba mi" - Matt. 26:29
1. OJO ko, ase na leyi

   Mo f’ara mi fun nyin

   E wo, mo f’eje mi fun nyin

   Lati ra nyin pada.


2. O di nu joba Baba mi

   Ki mto tun ba nyin mu 

   Ghana ekun ko ni si mo 

   A o ma yo titi.


3. Titi l'ao ma je onje yi

   K’o to di igba na

   Ka gbogb’aiye l’opolopo 

   Y’o ma je y’o ma mu.


4. Bukun atorunwa y'o ma 

   Wa lor’awon t‘o nje 

   Ngo gbe or’ite Baba mi 

   Ma pes’aye fun won.


5. Sugbon nisisiyi ago 

   Kikoro l'em'o mu 

   Emi o mu nitori nyin 

   Ago ‘rora iku.

6. E ko le mo banuje Mi 

   E ko ti r'ogo Mi

   Sugbon e ma s’eyi titi 

   K'e ma fi ranti Mi. Amin

English »

Update Hymn