HYMN 66

O.t. H.C 152 C.M (FE 84)
"Kini ki emi ki o se lati la?" - Ise 16:301. IGBALA ni, igbala ni

   Awa elese nfe

   Nitori ninu buburu

   T‘a se l‘awa nsegbe.


2. lse owo wa ti a nse

   O nwi nigbagbogbo

   Pe, igbala ko si nibe

   Ise ko le gba ni.


3. Awa nsebo, awa nrubo

   A nkorin, a si njo
  
  Sugbon a ko ri igbala

  Ninu gbogbo wonyi.


4. Nibo ni igbala gbe wa?

   Fi han ni, fi han ni

   B‘o wa loke, bi isale

   B'o ba mo, wi fun wa.


5. Jesu ni se Olugbala

   Jesu I'Oluwa wa;

   lgbala wa li owo Re

   Fun awa elese.


6. Wa nisisyi, wa loro

   lfe wa ninu Re,

   Enyin ti o buru l’ O npe

   E wa gba igbala. Amin

English »

Update Hymn