HYMN 665

L.M. (FE 691)
“Ibura, isepe ati Ipe oruko, Olorun
lasan, ese nla ni”1. AWON Angeli li orun 

   Nyin O logo, Olorun wa, 

   Iwuwo opa binu Re 

   Ndamu esu l’orun egbe.


2. Gbogbo enyin omo-komo 

   Asepe ati abura

   E se ranti ofin keta

   Ke bowo f’Oko Olorun.


3. Nwon o se le duro, Baba 

   Niwaju agbara nla Re! 

   Awon alaiberu Olorun 

   Yio lo si orun egbe!


4. Nibiti ki y’o si omi

   Ti y’o pa ongbe ofun won 

   Emi y’o o ma yin O titi

   Bi ngo ti ma yin li orun.


5. lbanuje nla ni fun mi 

   Lati gbo oro buburu

   Ti awon omokomo nso 

   Si Eledumare Baba!


6. Gbogbo won ni ngo ko l’ore

   Awon alaiberu Olorun

   Ti nwon np’oruko Re lasan

   Ti nwon mbura, ti nwon nsepe. Amin

English »

Update Hymn