HYMN 666

C.M. (FE 692)
"Egbe buburu ko se ko"1. AWON asepe, abura 

   At’awon onija

  Ni ijo kan pelu abo 

  Niki y’o je s’owo won.


2. Orin buburu ti nwon nko 

   Je rira l’eti mi

   K’iru oro buburu won 

   Mase t’enu mi bo.


3. Awon alailero omo 

   Awon Omo-komo

   Ki y’o f;’ijo kan j'egbe mi 

   A f‘ologbon omo.


4. Alailojuti omo kan 

   Ni b‘awon t'o ku je 

   Elekuru obuko kan 

   Ni ko orun w’agbo.


5. Ma je kl nk'egbe buburu 

   Olorun Oluwa,

   Ki nma si si ninu won

   Ti nlo s'orun egbe! Amin

English »

Update Hymn