HYMN 667

C.M.S 476, 623, t.C 506 L.M (FE 693)
"Mo si ri awon oku ewe......nwon 
duro niwaju Olorun” - Ifi.20:121. AWON kekeke wo l’eyi 

   T'nwon tete l’ajo aiye ja 

   Ti nwon si de ‘bugbe ogo 

   Eyiti nwon ti nf‘oju si?


2. Emi t’oke Sioni wa 

   Emi lati ile India

   Emi t’ile Afrika wa 

   Emi lat’ erekusu ni.


3. Irin ajo wa ti koja 

   Ekun ati irora tan

   A jumo pade nikehin 

   Li enu ibode own.


4. A nreti lati gbo pe, ‘Wa 

   Asegun ese on iku

  Gb’ori nyin soke, ilekun 

  K'awon ero ewe wole. Amin

English »

Update Hymn