HYMN 669

Tune t.H.36. L.M. (FE 695)
"Iro pipa! ese nla ni!"1. B’O ti dun to lat’ewe lo! 

   K’a fi ipa ogbon s’ona

   K‘a je olotito omo 

   K'araiye le f’okan tan wa.


2. A ko le gbekel’opuro 

   B’o tile pada s‘otito 

   B’enia se buburu kan 

   T’o si puro a di meji.


3. B’iro ti j’ohun rira to 

   L’Olorun fi han ‘nu Oro re 

   Iku-oro Anania

   Se n’tori ‘iro pipa ni.


4. Safira aya re pelu 

   Bi o ti njeri oko re 

   L’ogedengbe ko l’o Iule 

   Be ki t' ko t’aya ku si?


5. Oluwa y’o n’inu didun 

   S’enikeni ti ns’otito 

   Y'o si l’awon opuro lo 

   Sinu adagun ina.


6. Iro gbogbo t’enia npa

   L’Olorun nko s'inu iwe

   Ngo k’ahon mi ni ijanu

   Ki nma ba ku s’orun egbe. Amin

English »

Update Hymn