HYMN 670

C.M.S 460 t. H.C 506 C.M (FE 696)
“Omo na si dagba o si le l'akan."
- Luku.2:401. BI osun gbede eti do 

   Tutu mini-mini 

   B’igbo dudu eti omi 

   B'itanna ipado.


2. Be l'omo na yio dagba 

   Ti nrin l‘ona rere 

   T’okan re nfa si Olorun 

   Lat‘igba ewe re.


3. Ewe tutu l'eba odo 

   B'o pe, a re danu 

   Be n’itanna ipa omi 

   Si nre l‘akoko Re.


4. lbukun ni fun omo na 

   Ti nrin l‘ona Baba 

   Oba ti ki pa lpo da 

   Eni Mimo lailai.


5. Oluwa, Wo la gbekele

   Fun wa l‘ore ofe

   L’ewe, l‘agba ati n’iku 

   Pa wa mo b'omo Re. Amin

English »

Update Hymn