HYMN 682

C.M.S 486 P.M (FE 707)
“Ojo nlo, ojiji ale na jade" - Jer. 6:41. OJ’ON lo, 

   Jesu, Baba

   Boju Re w‘emi omo Re.


2. Wo Imole

   Se ‘toju mi

   Tan imole Re yi mi ka.


3. Olugbala

   Nko ni beru

   Nitori O wa lodo mi.


4. Nigbagbogbo

   Ni oju Re

   Nso mi, gbat’ enikan ko si.


5. Nigbagbogbo

   Ni eti Re,

   Nsi si adura omode.


6. Nitorina

   Laisi foiya

   Mo sun, mo si simi le O.


7. Baba, Omo

   Emi Mimo

   Ni iyin ye I‘orun, laiye. Amin

English »

Update Hymn