HYMN 685

C.M.S 482 t. H.C. 36.8s (FE 710)
"E fi iberu sin Oluwa” - Ps. 2:111. OMODE, e sunm’ Olorun 

   Pelu irele at’eru

   Ki ekun gbogbo wole fun 

   Olugbala at'Ore wa.


2. Oluwa, je k’anu Re nla 

   Mu wa kun fun ope si O

   Ati b‘a ti nrin lo laiye 
 
   K‘a ma ri opo anu gba.


3. Oluwa! m‘ero buburu

   Jina rere si okan wa 

   L;'oiujumo fun wa I‘Ogbon 

   Lati yan ona toro ni.


4. lgba aisan at‘ilera 

   lgba aini tabi oro

   Ati lakoko iku wa

   Fi agbara Tire gba wa. Amin
 

English »

Update Hymn