HYMN 703

1. O ha ngbekele Jesu n’gbogbo‘ona re

   O ha nd'otun lokan re lojojumo

   O ha joni eyin Re? ye oro Re wo 

   Y’o fun o l'Emi Mimo lopolopo.

Egbe: Lopolopo si, lopolopo si

      Ki won Ie ni iye si lopolopo si

      Lopolopo si, Iopolopo si

      Ki won le ni iye si Iopolopo.


2. Fun oju rere Re, gbe oko Re ga 

   Olugbala wa to t’orun sokale 

   K'awon ayanfe Re juba oro Re 

   Eni ra wa pada nipa eje Re.

Egbe: Lopolopo si, lopolopo si...


3. Wa pelu igbagbo, wa je ipe Re 

   Eyin t’a mbukun, jowo ara yin fun 

   Jesu, y‘o gb'eni t'o sda wa sodo Re 

   T'o da ‘bukun Re lu o lopolopo.

Egbe: Lopolopo si, lopolopo si

      Ki won Ie ni iye si lopolopo si

      Lopolopo si, Iopolopo si

      Ki won le ni iye si Iopolopo. Amin

English »

Update Hymn