HYMN 705

S.M. (FE 732)
"A si gbo iro awon Keburu titi de
agbala ode” - Eze. 10:51. ARA, e ba wa yo 

   Ka jo d’orin wa po 

   Nipa ti Kerubu t’a ri 

   T’o si s’oju emi.


2. Gbogbo Egbe Serafu 

   Baba Aladura 

   Captain ayo li eyi je 

   Pe Kerubu tun de.


3. E wa ka s’owo po 

   K’a yin Baba l’oke 

   K‘a fi gbogbo keta sile 

   K‘okan wa kun f’ayo.


4. Egbe Aladura

   E ku afojuba

   Egbe lgbimo Serafu 

   E ku ayo okan.


5. Enyin Egbe Akorin

   E tun ohun nyin se

   Ki fere dun, ki duru dun 

   Ki a jumo ho ye.


6. Kerubu Serafu 

   Awon l’o gbode kan 

   Ase, Oluwa l’eyi je 

   Ko s’egbe to dun to.


7. Orin Halleluya

   L’a wa yio ko l’orun

   Halle! Halle! ! Halleluya! ! ! 

   Amin, Amin, Ase. Amin

English »

Update Hymn