HYMN 735

C.M. (FE 761)
“Ma beru ohun ti wio yio je niya iwo 
se oloto de oju iku, emi yio si fi ade 
iye fun o" - Ifi. 2:10 
Tune: lsun kan wa to kun f’eje1. ENYlN om’egbe Serafu 

   E ko le p’e o ko ‘ya 

   Enyin om eghe Kerubu 

   E ko le pe e o ko ya.


2. Enyin om'ogun gbala yi 

   E ko le pe e o k’egan 

   E ko le ko ‘nunibini 

   Ati keta gbogbo.


3. E gb’ohun Olugbala wa 

   B’o ti nwi jeje pe

   Ranti mi lor’agbelebu 

   At, owo at'ese.


4. Bi a ba foriti ‘ponju 

   Ti a si ru ‘tiju

   Ade ogo ‘rawo Owuro 

   Y’o je tiwa n‘kehin.


5. Ao pelu awon t’orun 
 
   Lati ma juba Re

   A o si ma ko orin Mose 

   Ati t’Odagutan.


6. Orin Halle, Halleluya! 

   lyin si Oba wa 

   Metalokan Aiyeraiye 

   Baba, Omo, Emi. Amin

English »

Update Hymn