HYMN 742

8s 4s (FE 768)
"Jeki Israeli ki o yo si eniti o da”
 - Ps. 149:21. KERUBU ati/Serafu 

   Nwon nyin Baba/wa loke 

   Baba Mimo, Baba/ogo 

   ko so wa.


2. Jesu Olori/Egbe wa 

   O ti ji di/de loni 

   Kerubu ati Se/rafu 

   Kun fun ayo.


3. Jehovah Ji/reh Oba 

   Jehovah Nis/si Baba 

   Jehovah-Rufi/yio so wa 

   Titi lailai.


4. Enyin omo egbe/Kerubu 

   To wa lori/’le aiye
 
   Jesu Olori Egbe wa, 

   Jinde loni.


5. Egbe to ndamu/nisiyi 

   To si ngbadu/ra kikan 

   Yio bu s’orin a/yo lojo 

   Ajinde.


6. Egbe Mimo to/wa l’oke 

   Nwon nyin Baba/wa logo 

   E je k’awa ta/wa laiye 

   Ka si mura.


7. Aje, Oso ko ni/ipa kan 

   Lori Egbe/Kerubu, Seraf 

   Jesu Olori/Egbe wa,

   O ti segun. Amin

English »

Update Hymn