HYMN 747

C.M.S 138 H.C 123 10s 11s (FE 775)
“Olubukun ni oruko Oluwa Iati 
igbayi Io, ati titi Iai." - Ps.113:21. RANSE Olorun, e ma kede Re

   E ma k’okiki oruko Re nla 

   E gbe oruko Jesu asegun ga 

   Ijoba Re l’ogo ohun gbogbo.


2. Olodumare, O njoba loke

   O si sunmo wa, O mbe lodo wa, 

   Ijo nla ni y‘o korin isegun Re 

   O njewo pe, ti Jesu ni igbala.


3. lgbala ni t’Olorun t‘o gunwa 

   Gbogb' aiye kigbe, e f’Ola f’Omo 

   Iyin Jesu nigbagbogbo Angel nke 

   N’idojubole, nwon nsin Od’agutan.


4. E jek’awa sin, k’a f’iyin Re fun 

   Ogo, agbara, ogbon at’ipa

   Ola at’ibukun, pel‘awon Angel,

   Ope ti ko lopin at’ife titi. Amin

English »

Update Hymn