HYMN 762

H.C 541 6s (FE 796)
"Mo gbo ohuu kan Iati orun wa nwipe 
ibukun ni fun oku ti o ku nipa ti Oluwa"
- Ifi.14:131. IBUKUN ni f'oku 

   T'o simi le Jesu

   Awon t’o gb‘ori won 

   Le okan aiya Re.


2. Iran ‘bukun l'eyi 

   Ko si ‘boju larin

   Nwon ri En‘imole 

   Ti nwon ti fe lairi.


3. Nwon bo Iowo aiye

   Pelu aniyan re

   Nwon bo lowo ewu 

   T’o nrin l'osan, l’oru.


4. Lori iboji won

   L'awa nsokun loni 

   Nwon j'eni ire fun wa

   T'a kl y'o gbagbe lai.


5. A k' y'o gbohun won mo

   Ohun ife didun

   Lat’ oni lo, aiye

   Ki o tun mo won mo.


6. Enyin oninure 

   E fi wa sile lo

   Ao sokun nyin titi 

   Jesu pa sokun ri.


7. Sugbon a fe gbohun 

   Olodumare na

   Y’o ko, y‘o si wipe 

   E dide, e si yo. Amin

English »

Update Hymn