HYMN 770

C.M.S 592 S.M. (FE 804)
"E ma ko won lati ma kiyesi
ohun gbogbo" - Matt. 28:201. ENYIN ‘ranse Kristi 

   Gbo ohun ipe Re

   E tele bi t’o fonahan 

   A npe nyin s‘ona Re.


2. Baba ti enyin nsin 

   O n’ipa to fun nyn 

   N‘igbekele ileri Re 

   E ja bi okunrin.

3. Lo f’Olugbala han 

   Ati anu nla Re

   F’awon otosi elese 

   Ninu omo Adam.


4. L’oruko Jesu wa

   A ki nyin, Ona re!

   A mbe Enit’ o ran nyin lo 

   K’O busi ise nyin. Amin

English »

Update Hymn