HYMN 782

C.M.S 545 t.H.C 60 7s (FE 816)
"Emi ki gbe pe O, Oluwa” - Ps.30:8
Tune: A gboju s’oke si O1. WA, Jesu fi ara han,

   Wa, jek'okan wa mo O 

   Wa, mu gbogb’okan gbona 

   Wa, bukun wa k‘a to lo.


2. Wa, f’aiya wa n’isimi 

   Wa, k’a d’alabukunfun 

   Wa, soro alafia

   Wa, busi igbagbo wa.


3. Wa, le ‘siyemeji lo 

   Wa, ko wa b’a ti bebe 

   Wa, fun okan wa n'ife 

   Wa, fa okan wa soke.


4. Wa, so f‘okan wa k‘o yo 

   Wa, wipe “Wo ni mo yan 

   Wa, p'awon agbo Re mo 

   Wa, sure f’agutan Re. Amin

English »

Update Hymn