HYMN 797

t.s. 747 886 (FE 832) 8.8.6
"Bi o se t'emi ati iIe mi ni, Oluwa
l'awa o ma sin" - Jos 24:15 
Tune: “Lehin aye buburu yi”1.  EMI at'ara ile mi

Yio ma sin Oluwa wa 

Sugbon emi papa;

Yio f'iwa at'oro han 

Pe mo mo Oluwa t’orun 

Mo nfi toto sin.


2.  Em’o f’apere ‘re le 'le 

Ngo mu idena na kuro

Lodo om’odo mi

Ngo f’ise won han n’iwa mi 

Sibe n‘nu ‘se mi ki nsi ni 

Ola na ti ife.


3.  Emi ki y’o soro gb’ipe 

Emi ki y’o pe tu ninu 

Om’ehin Olorun

Mo si fe je eni mimo 

Ki nsi fa gbogbo ile mi 

S’oju ona orun.


4.  Jesu, b’O ba da ‘na fe na 

Ohun elo t’iwo fe lo 

Gba s’owo ara Re!

Sise ife rere n’nu mi

Ki nfi b’ onigbagbo toto 

Ti ngbe l’aiye han won.


5.  Fun mi l’ore-ofe toto 

Nje! Emi de lati jeri 

Yanu oruko Re

Ti o gba mi l’owo egbe 

Ire eyi t’a mo l’okan

Ti gbogb’ahon le so.


6.  Emi t’o bo lowo ese

Mo wa lati gba ‘le mi la

Ki nwasu dariji

F’omo, f’aya, f’omo-do mi 

Lati mu won to ‘na rere

Lo si orun mimo.  Amin

English »

Update Hymn