HYMN 821

H.C No 57 Edn. 6.8s (FE 857) 
"Nitorlpe apata won ko dabi apala wa
- Deut. 32:31
Tune: lgbagbo mi duro lori1. E jek‘ a yin Olugbala 

   T'o da Emi wa si di oni

   Nitori a ko mo ojo

   T'o mbo wa se 'dajo aiye 

  Ojo kan mbo gba aiye ba pin 

  Kerubu yio ko 'rin Alleuyah.


2. Ojo ‘dajo ojo eru

   Gba Jesu yio ya Agutan Re 

   Kuro ninu agbo esu

   Gbana ipe nla yio si dun 

   Gbogbo aiye yio wa si idajo 

   Serafu yio ko ‘rin Alleluyah.


3. Awon elese yio fe sa

   Kuro niwaju Olugbala 

   Sugbon iye ko ni si mo 

   Nwon yio ke gba mi Oluwa 

   Sugbon ojo anu koja 

   Kerubu yio ma ko Alleluyah.


4. Ara mi jek’ a gba adura 

   S'Olorun Metalokan

   Tori on lo da aiye

   Ati gbogbo eda ‘nu re

   Yio si ko awon Tire jo 

   Lati ma korin niwaju ite. Amin

English »

Update Hymn