HYMN 862

15.6.15.6 CM1. OLUS’AGUTAN, toju wa,

   Li ojo ibi yi,

   Fun gbogbo omo-ehin Re, 

   N’ ipa lati sona.


2. B’ igba idanwo wa ba pe, 

   T’ iponju po fun wa,

   Jek‘ emi wa sirni le O,

   L’ adura aisimi.


3. F’ ore-ofe emi ebe, 

   Fun wa nipa ‘gbagbo; 

   K’a du titi ao r’oju Re, 

   T’ ao si mo oko Re.


4. Titi O fun wa l’ara Re, 

   Ati ife pipe

   K’eyije igbe gbogbo wa, 

   Nki o je ki O lo.


5. O ki o lo, bikosepe,

   O s’oko Re fun mi,

   K’ O f’igbala Re bukun mi, 

   Si jeki ndabi Re.


6. Jeki nr’oju Re kedere

   ‘Gba m’ ba d’ori-oke, 

   Nibit’ a r’ohun t’a gbagbo, 

   T’adura di iyin. Amin

English »

Update Hymn